"Ọmọ Mí Òwón" lyrics

"Ọmọ Mí Òwón"

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Bàbá rẹ ò gbọ̀n tóó
Dáríjì mí o
Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Kò sẹnì gbọn jù Ọlọ́run lọ
Ṣé bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Òrìṣà òkè
Oh, eh, Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè
Òrìṣà òkè

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Ọlú ọ̀run gan-an ò gbọ́n tó
Kò sí bo ṣe ṣe tó ma t'ènìyàn
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Ọmọ mi ọ̀wọ́n
Kò s'ẹ́ni gbọ́n ju Ọlú ọ̀run lọ
Ṣe bó ti mọ
Ó ma tó ò
Ọmọ mi ọ̀wọ́n

Bò n là kàkà
Àwọn alaálè
Wọn ò ní f'orí j'ọ̀ṣíká
A ò ṣè kà
A ò parọ́
A ò parọ́ o
Ah, a ma là
A ma là
A ma là


You May Also Like
Teni - "Billionaire" Doctor Dolor Entertainment Teni Makanaki Wanna make love on the moon Dancing to my tunes It's it too much, is not too much I wanna be on Forbes list If wishes were horses Is it too much, it's not...
Falz - "Child Of The World" Yeah, go, ah Apple of her mothers eye, she be trophy daughter Mommy raised her daddy never dropped a dollar Daddy ran away didn't wanna have a child Mummy wasn't ready still remember how she cried...
Simi - "Charlie" I've been trying To write you a song for years But I'm not sure what to say Can't stop crying Although you been gone for years I wish that you could have stayed See, I walked down the aisle just the...
Lil Kesh - "Ishe" My baby chikito from the down town side She dey charge me up when I get no bar Motivate me any time I feel so down I cannot forget all your sacrifice Ise lo s'omo nu bi oko Forgive me, Ise lo s'omo...
Aṣa & The Cavemen. - "Good Times" Oh nah na na no Oh na na na no na no Oh nah na na no Oh na na na no na no Mm mm E yin mm E yin mo ma o My good friend They say show me your friend Will tell who you are Oh my friend I no fi deny Ibu...