"Jungle" lyrics
"Jungle"
IG no be low-key (Ọlọhun)
Ace and booty when I′m rocking (ájè)
Daily, mi hustle, for here, no dulling (City)
After, dem go say the boy dey lucky
Ah, but nobody wey dey see all of this struggle
Trying or die trying for this jungle (Ọlọhun)
I be hustler, tell me anything me can't do
Èmi young rich nigga, Shatta Bandle
Ọmọ, miò ṣ′èrè
Zero Pa, ò má kèrè
Ẹ sọ fun wọn, k'ọmá lọ gun iyàn mi kèrè
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹkàn pèrè
Miò ṣ'èrè
Zero Pa, ò má kèrè
Ẹ sọ fun wọn, k′ọmá lọ gun yàn mi kèrè
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹyọkàn pèrè
Ò máránmá, ò ṣápra-pra
Mò sá f′ẹjọ, ọmọ, mòti shamaya
Ṣèbi tòri òwò má ni mò ṣè dángbáná ò
Jọwọ, ṣè t'èmi, iwọ lò ṣè ti lágbájá
Wọn ni "kin má párá cetamol"
Ṣèbi tòri ẹ ni mò lò Paracetamol
We no belleful, although, we no dey hungry
See me rocking High Fashion, Rahman Jago
Ọmọ, miò ṣ′èrè (Hmm-mm)
Zero Pa, ò má kèrè (Hmm-mm)
Ẹ sọ fun wọn, k'ọmá lọ gun iyàn mi kèrè (Hmm-mm)
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹkàn pèrè
Miò ṣ′èrè
Zero Pa, ò má kèrè
Ẹ sọ fun wọn, k'ọmá lọ gun iyàn mi kèrè
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹyọkàn pèrè
Wetin be the 411? Make I know one, two
Many wọn wá wá like a bandit
Èmi ò mà r′áyè jágbájántis
I dey deliver oh, I render your service
You know we dey Poco Lee, any, we gbègẹ
Ábi iwọ l'òmá sọ pè áyè lọni Peripẹ ò
Bọbọ, dupẹ f'ọjọ ti ò ri jẹ
Málọ dè′bẹ ò, ábọwábá l′áṣèlẹ ò
Ọmọ, miò ṣ'èrè
Zero Pa, ò má kèrè
Ẹ sọ fun wọn, k′ọmá lọ gun iyàn mi kèrè
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹkàn pèrè
Miò ṣ'èrè
Zero Pa, ò má kèrè
Ẹ sọ fun wọn, k′ọmá lọ gun iyàn mi kèrè
Wọn má jẹ ẹyọkàn pèrè, ẹyọkàn pèrè
- AZLyrics
- B
- Balloranking Lyrics
You May Also Like
Tml Vibez & Victony - "Hello" Omo pupa bi custard
Iwo nikan lo le gbemidebe all night
Gbemisori one time
Tiba wa je kolo omo I be bastard o
Wahala wahala
Omo me I like your style wahala
Omo je ka soro
Je ka soro malo malo
Hello...
Seyi Vibez - "Hushpuppi" Yo dibs
God Sent, I'm a blessing
Otedola life is Eazi
Beere mi, Won mo iru mi
Roll me a blunt baby Jummy
What is a bumbum in Zulu?
Is bunu is kulu
South Africa booty buru
Girl your body is a...
Zlatan & Seyi Vibez - "Let There Be Light" Billion dollar baby omo dudu bi koro ishin
Won fe lami egbamiss
I don dey see screenshot won shi n reset o ti n order
Kaka emi oni joba
Pussy cat put in Russia
Simultaneous equation gats balance
Find...
DaVido - "I Know Who I Be" Who am I? I'm a bad guy
My designer, waka-waka
Balenciaga and Prada
You must have gone insane if you think your story
Your story is my story
I know who I be (I know who I be)
Who am I? I'm a bad...
L.A.X & Tml Vibez - "MAGAA" Have you heard about me?
Lakọ mo dúró
No time for story
No time for story o
Baby ṣa wojú mí o
Desire lojú mi o
I give you everything
Ohh ahh
Jẹ ka ma lọ, don't you leave me
If I dey pray ṣa ma...