"Oil And Gas" lyrics

"Oil And Gas"

Igbe, igbe, igbe-gbe-gbe, igbe
Egbe, egbe-gbe-gbe, egbe
Oga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá

Tony Elumelu
Wá ba mi jó sílú
Femi Otedola
È̩ ná mí ní dollar
Asiwaju Jagaban
Ghana must go bag
Oba Elegushi
È̩ ná mí n kukushi

Asiwaju tí bínú, yeh
Wọn ni mi o mọ law
Wọn ni kín ye gbé Ghana must go
Wá s'ilé àwọn ni Bourdillon
Omo, omo bullion van, yei
L'ọfí gbé wá fún mi, eh

Dapo Abiodun
O yí bíríbírí kàn mi
Oga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá

Èyàn Shina Peller
My honourable
MC Musiliu, eh
È̩yín lẹnu dá kú
IBD Dende
Áfún ni mà wo bẹ, yei

Seyi Tinubu
Ògo Lagos, oun l'ojú Eko
O mọ̀ Kunle Poly
O mọ̀ 1805
O mọ̀ Igbalode
Gucci, Gucci, èyàn Hushpuppi

Àwa lá ni Lagos
(Na we get this Lagos)
Ẹyín lẹ n'ìlé yín
(Ẹyín lẹ ni Lekki)
O mọ̀ Dangote
Cementi wọn lọ fí kọ ílé yín
Ọmọ ase!

Oga mi ẹnu gbẹ
Ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
Alaye, ẹnu gbẹ
Walahi ẹnu gbẹ

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn
Ẹ le ná wó yẹn tàn
Ẹ le l'epo yẹn tàn, eh

Owó wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín ná
Epo wa lọwọ́ yín
Ẹ jẹ ká báyín lá

Maintain bi t'Olu
Ko ye jó Yahooze
T'o ba Sanwo Olu
Wa ṣa sanwó toll gate, yei

(Bring me my cooler, yo!)

Maintain bi t'Olu
Ko ye jó Yahooze
T'o ba Sanwo Olu
Wa ṣa sanwó toll gate, yei


Writer(s): Olamide Adedeji
You May Also Like
Rema - "Lady" Another Banger! Buzz brain Buzz brain yeah Can't stop can't stop yeah Rema Rema yeah Yeah The moment I see you na up NEPA o Lady Ooo my Lady Oo Oo woah This your body go cause yakpa o yeah Baby Ooo...
Mayorkun - "Your Body" Fresh, Yanaur Of Lagos (damn) Special! (My body on your body o...) Tell me wetin dey Your body, your body Na your body girl your body o Sekin kaye fun e t'oro yo di o (oloun maje) Tell me wetin dey...
Joeboy - "Fààjí" Aye, aye, aye, aye, aye (It's Joe) (Joeboy pon this) Too fresh and clean don't stain my white Chopping money, flexing life (Yeah) I can do as I like Make I dance and party all night Mole jo, tori mi...
Shallipopi - "Free Service" Yo, X They call me Shallipopi Day break, everywhere burst Everywhere stew, money dey rush Vacation for me and all my blood As I dey, credit alert dey drop You can't love me, it's not by force If not...
Crayon & Rema - "Too Correct" Wawawa Another banger I dey for corner when I sight you but you no really know I wear my dark shades, suppose know how superstar thing dey go Inside my heart I dey love but for my face e no dey...